Aimoye Lyrics by Kayode
“Aimoye” is a single by Nigerian artist Kayode, released on March 12, 2026. Kayode delivers this brand new banger titled “Aimoye ” a free mp3 song.
Aimoye Lyrics by Kayode
Intro
Aimoye awọn eniyan, to ti lọ nile aye
Aimo, aimoye awọn eniyan
To ti lọ n, to ti lọ n
Aimoye awọn eniyan, to ti lọ nile aye
Aimo, aimoye awọn eniyan
To ti lọ n, to ti lọ n
Aimoye awọn eniyan, to ti lọ nile aye
Aimo, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n, to ti lọ n
Aimoye awọn eniyan (Aimoye), to ti lọ nile aye (Aimoye)
Aimo, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n (K, K, Kay’)
Verse 1
Yeah, kilowade gan-na?
You know you be feeling the boy’s swag
Ice on my neck tan-na (Ice)
Bawo lo ṣe’n wa gan-na
Ko si n’ tẹ ma ṣe, on God (Àgé)
Why you come dey para, para, para
Para, para, para, better comport, comport (Abeg, abеg)
Me I no fit gree, me I no fit wait
Ṣe you see mе do like dondos?
Ọmọ ọgbọn ni mi, I no even like to dey do Oscroh
Aimoye awọn, Aimoye
Nigga toti wa to ti fọ, to ti lọ
T’ọmọ l’ọmọ oti Bob (Bob), ma lọ ma gbogbo si, gbogbo si
Chorus
Aimoye awọn eniyan (Yeah, aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n, to ti lọ n (Yeah, yeah)
Aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n, to ti lọ n
Aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n, to ti lọ n (Yeah, yeah)
Aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n, to ti lọ n
Verse 2
Ọlọrun lo mọ o, ọlọrun lo mọ o, ah
Ẹda to n ṣ’ika, t’aye ro b’oṣe’re o
Oluwa lo ye o (Oluwa lo ye o), ah (Kay Kay)
Mo k’àwọn ènìyàn tàn, ọmọ ni mo ti binu pé kí ni mo jẹ? (Ki ni mo)
Ki ni mi fa? Ki ni mumu? (Ah)
Wọn ni bawo ni, bawo ni, ba, wọn ni ba ni
Ṣa I don bail my p’emi dẹbẹ
Enemies, wey dey bail me wa lẹ (Like, like)
Ọlọrun lo mọ o
Chorus
Aimoye awọn eniyan (Yeah, aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n, to ti lọ n (Yeah, yeah)
Aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n, to ti lọ n
Aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n, to ti lọ n (Yeah, yeah)
Aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ nile aye (Yeah, aimoye)
Aimo, aimoye awọn eniyan (Aimoye)
To ti lọ n, to ti lọ n
You May Also like: